Bad government

Omo Yoruba ni mi, mo fe so die ninu iriri mi ni orile-ede yen ti won pe ni Naijiria je orile-ede ti ijoba je isoro gbogbo araalu, Naijiria ti se pupo ni aye wakati, mo ranti pe igba kan wa ti mo. Mo n gbiyanju lati di jagunjagun Naijiria Mo ni asopọ pẹlu ọgagun kan ti o fẹ ran emi naa lọwọ lati di ọmọ ogun Naijiria, ṣugbọn ko pẹ pupọ awọn oṣiṣẹ ologun gbogbogbo sọ pe, o yẹ ki o wa nkan miiran lati ṣe Emi kii yoo gba ọ ni imọran lati darapọ mọ Soja Naijiria paapaa emi temi ni mo fe fi ise naa sile, looto okunrin yii fi ise naa sile, mo si bi i leere pe kilode ti e fi kuro ninu ise naa, o ni e je ka gbagbe pe, Naijiria iwa jegudujera dabi ile ejo asiri.

Categoria:
Artes e Cultura