Chief Temitayo A. O Odutayo - Interview on Clevenard Radio 1

Genre:
Interviews 
About:

The guest on the programme today was Chief Temitayo A.O Odutayo ( Oluomo of Yoruba South Africa). He took us through Yoruba one voice and how the nation will stand alone as he believes Yoruba's are being short-changed in Nigeria.

Alejo lori eto loni ni Chief Temitayo A.O Odutayo (Oluomo of Yoruba South Africa). won soro ni pa bi Yoruba yo se da duro nitoripe asiko ti to. Won se awon alaye yi ni ekun rere , paapa juro ni pa awon Fulani ajini gbe ati wipe ijoba apapo ko da si gbogbo oun ti awon Fulani nse ni ile Oodua.

Country:
South Africa